Introducing the children's laptop from One Laptop per Child—a potent learning tool created expressly for the world's poorest children living in its most remote environments. The laptop was designed collaboratively by experts from both academia and industry, bringing to bear both extraordinary talent and many decades of collective field experience in every aspect of this non-profit humanitarian project. The result is a unique harmony of form and function; a flexible, ultra low-cost, power-efficient, responsive, and durable machine with which nations of the emerging world can leapfrog decades of development—immediately transforming the content and quality of their children's learning.
ILÉKọ̀ǹpútà Alágbèéká fún Ọmọ Kọ̀ọ̀kan (OLPC) jẹ́ àjọ aṣẹ̀dá lá́ńfààní tó fira wọn jìn fún ìwádìí-ìjìnlẹ̀ láti lè ṣe kọ̀ǹ́pútà alágbèéká $100—ìmọ̀-ẹ̀rọ tí ó lè mú ìyípadà ọ̀tun bá bí a ṣe ń kọ́ àwọn ọmọdé àgbáyé lẹ́kọ̀ọ́. Nicholas Negroponte tó jẹ́ alága OLPC ní àjọ World Economic Forum ní ìlú Davos, Switzerland ní Jánúárì 2005 ló kọ́kọ́ kéde ète yìí.
Ibi tí a fẹ́dé: ni láti lè pèsè àwọn àǹfààní fún àwọn ọmọdé kárí-ayé láti lè ṣàbẹ̀wò, àṣerò kí wọ́n sì lè fi èrò-ọkàn wọn hàn.
Jọ̀wọ́ kíyèsí pé àwọn kọ̀ǹpútà alágbèéká $100 náà—kò tí ì kúrò níbi tí a ti ń ṣe wọ́n—a kò dẹ̀ ní tà wọ́n. Àwọn ilé-ìwé nìkan la máa pín àwọn kọ̀ǹpútà alágbèéká náà fún tààrà nípasẹ̀ àwọn ète ìjọba ńlá.
WIKIWIKI
WIKI là ń lò fún ìdáwọ́lé náà, níbẹ̀ la sì máa ń pe ilù sí láti jíròrò: (1)ẹ̀yà-ara kọ̀ǹpútà afojúrí; (2) ẹ̀yà-ara kọ̀ǹpùtà àìfojúrí; (3) àkóónú ètó-ẹ̀kọ́; (4) àwọn ètò ìfilọ́lẹ̀; (5) bí ẹ ṣe lè dá si; àti (6) ṣàfikún àwọn ìbéèrè sí FAQ wa.
Bẹ WIKI wò nípa títẹ̀ lórí wúnrẹ̀n àtòjọ-ẹ̀yàn WIKI.
ÌRÒYÌN ÌLÚÌRÒYÌN ÌLÚ
Ìṣàfikún ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀ la máa ń lò fún Ilú OLPC tí a lè wòye nípa títẹ̀ lórí wúnrẹ̀n àtòjọ-ẹ̀yàn ÌRÒYÌN ÌLÚ.
FAQFAQ
Kí ni Kọ̀ǹpútà Alágbèéká $100 náà wà fún gan? Ẹ̀rọ $100 tí à ń gbèrò náà dá lé Linux pẹ̀lú ìṣàfihàn móòdù oníméjì—àwọn méjèèjì ló ní àwọ̀ kíkún, móòdù Ẹ̀rọ $100 tí à ń gbèrò náà dá lé Linux pẹ̀lú ìṣàfihàn móòdù oníméjì—àwọn méjèèjì ló ní àwọ̀ kíkún, móòdù transmissive DVD àti ẹ̀yàn ìṣàfihàn kejì tó lè tan òjìji dúdú àti funfun, tó si jẹ́ ìtànná oòrùn tó ṣeékà ní ìwọ̀n ìmúsí àwòrán 3×. Kọ̀ǹpútà alágbèéká náà máa ní elétò kọ̀ǹpútà 500MHz àti 128MB DRAM pẹ̀lú ọpọlọ Fíláàṣì 500MB, kò ní sí àwo dísíìkì ṣùgbọ́n ó máa ní àwọn ààlà-ìfibọ̀ USB mẹ́rin. Àwọn kọ̀ǹpútà alágbèéká náà máa ní bọ́dúbaǹdì aláìlókùn, èyí á gbà wọ́n láyè láti lè ṣiṣẹ́ papọ ní alátagbà agbègbè. Kọ̀ǹpútà alágbèéká kọ̀ọ̀kan á lè bá àwọn aládùúgbò tó súnmọ jù sọ̀rọ̀, ìṣẹ̀dá alátagbà agbègbè pàjáwìrì wáyé nì yẹn. Àwọn kọ̀ǹpútà alágbèéká náà máa lo agbá́ra àtinùdá (tó lè ká pọ̀)́ yóò sì lè ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun, kò kàn ní lè fi oye àkójọpọ̀-ẹ̀rí ńlá pamọ́ ni àti ẹ̀yàn ìṣàfihàn kejì tó jẹ́ òjìji dúdú àti funfun, tó si jẹ́ ìtànná oòrùn aṣeékà ní ìwọ̀n ìmúsí àwòrán 3×. Kọ̀ǹpútà alágbèéká náà máa ní elétò kọ̀ǹpútà 500MHz àti 128MB DRAM pẹ̀lú ọpọlọ Fíláàṣì 500MB, kò ní sí àwo dísíìkì ṣùgbọ́n ó máa ní àwọn ààlà-ìfibọ̀ USB mẹ́rin. Àwọn kọ̀ǹpútà alágbèéká náà máa ní bọ́dúbaǹdì aláìlókùn, èyí á gbà wọ́n láyè láti lè ṣiṣẹ́ papọ ní alátagbà agbègbè. Kọ̀ǹpútà alágbèéká kọ̀ọ̀kan á lè bá àwọn aládùúgbò tó súnmọ jù sọ̀rọ̀, ìṣẹ̀dá alátagbà agbègbè pàjáwìrì wáyé nì yẹn. Àwọn kọ̀ǹpútà alágbèéká náà máa lo agbá́ra àtinùdá (tó lè kápọ̀) yóò sì lè ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun, kò kàn ní lè fi oye àkójọpọ̀-ẹ̀rí ńlá pamọ́ ni.
Wo àwọn ìbéèrè wa tí wọ́n sábà máa ń bèrè nípa títẹ̀ lórí wúnrẹ̀n àtòjọ-ẹ̀yàn FAQ.
ÈNÌYÀNÀWỌN Ọ̀GÁ ILÉ-ÌWÉ
Nicholas Negroponte, Chairman
Antonio Battro, Chief Education Officer
Walter Bender, President, Software and Content
Michail Bletsas, Chief Connectivity Officer
David Cavallo, Director for Central and South America
Robert Fadel, Director of Finance and Operations
Mark Foster, VP of Engineering/Chief Architect
Jim Gettys, Vice President, Software Engineering
Khaled Hassounah, Director for Middle East and Africa
Mary Lou Jepsen, Chief Technology Officer
Charles Kane, Chief Financial Officer
Samuel J. Klein, Director of Content
Ivan Krstić, Director of Content Systems
Nia Lewis, Secretary of the Corporation,
ÀWỌN OLÙDÁMỌ̀RÀN
Rebecca Allen, Howard Anderson, José María Aznar, V. Michael Bove, Jr., Benjamin Mako Hill, William Kolb, Alan Kay, Ayo Kusamotu, Rodrigo Mesquita, Eben Moglen, Seymour Papert, Bruce Parker, Mitchel Resnick, Ted Selker, Larry Weber, and Barry Vercoe
Wo bios nípa títẹ̀ lórí wúnrẹ̀n àtòjọ-ẹ̀yàn ÈNÌYÀN.
ÌGBÉRÒYÌNJÁDE
Wo àtòjọ àwọn ìjáde ìròyìn nípa títẹ̀ lórí wúnrẹ̀n àtòjọ-ẹ̀yàn ÌGBÉRÒYÌNJÁDE.
ÌGBÉRÒYÌN WỌLÉÌGBÉRÒYÌN WỌLÉ

Ṣàgbéwọlé àwọn àwòrán (ó sì lè jẹ́ ẹ̀yà-ara kọ̀ǹpútà àìfojúrí àti àwọn nǹkan mìíràn) wà nílẹ̀, nípa títẹ̀ lórí wúnrẹ̀n àtòjọ-ẹ̀yàn ÀGBÉWỌLÉ.
MÁÀPÙMÁÀPÙ

A fi àwọ̀ kóòdù máàpù àgbáyé tiwa ṣe ìtọ́kasí: (àwọ̀ ewé) àwọn orílẹ̀-èdè tí a fẹ́ páílọ̀tì; (red) those countries we plan to include in the post-launch phase; (àwọ̀ ọsàn) àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n ti fi ìfẹ́ hàn si ní ìpele Ẹ̀ka-Ẹ̀kọ́ tàbí tó ga ju bẹ́ẹ̀ lọ; àti (yẹ́lò) àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n ń wá àtìlẹ́yìn ìjọba.
KÀN SÍ OLPCKÀN SÍ OLPC
info at laptop.org
One Laptop per Child
P.O. Box 425087
Cambridge, MA 02142
USA
niav at laptop.org
mailman.laptop.org/mailman/listinfo